SunoVideo

No Music Video Found

Amope Wa Ọlọrun (We Give Thanks to God)
Listen on Suno

Amope Wa Ọlọrun (We Give Thanks to God)

10
Artist:PGMiX
Duration:5:23
Tags:male vocals,female vocals,guitar,electronic,beat,wooro beat,highlife beat 120bpm
(Worship beat)
Amope wa Ọlọrun (2x)
Ajinde ati iye aye wa ooo
Amu iyin wa fun ooo

(Lead Vocal) 
Orun lati joba osan
Osupa lati joba oru
Nitori ti o seun
Nitori ti anu re duro lailai

All: Amope wa Ọlọrun (2x)
Ajinde ati iye aye wa ooo
Amu iyin wa fun ooo

(wooro beat start)
Verse 1 (Call \u0026 Response)
Call: Taba ni salaye
Ore ti Baba se fun wa
Enu wa kole royin tan
Ore ti Oluwa se fun wa o Baba
Kadupe! Kadupe! Kadupe!
Baba ose o, oseun seun
Ota reti ka subu
Baba lo n ko wa yo
Ero ota ni wipe
Ka jade, ka ma wole o Baba
Wo n gbin mopo sugbon ko jo
Ope lo ye Oluwa, oseun

(Chorus)
E fiyin fun Olorun
E je ka jo fiyin f'Olorun
Ope ati iyin fun Baba
Olore aikaika tan ni
Olorun ayo, a juba re (2x)

(Verse 2)
Female lead: Oni a o ni ruku wole
Be la o ni ruku jade
Ona gbogbo l'ope wa yio ja si
Eyi ni ipin wa ninu ijo VICEM
La'se n so wipe
Ope ni ohun ma da
F'Olorun mi, bi mo ba sope tan o
Ma si rerin ayo

(Chorus)
E fiyin fun Olorun
E je ka jo fiyin fun Olorun
Ope ati iyin fun Baba
Olore a ki i ka tan ni
Olorun ayo, a juba re (2x)

(Highlife Praise, 120bpm)

Male Lead: Ogo ni fun Oluwa
To se ohun nla
Ife lo mu ko fun wa ni
Omo re
Emi to fe mi re lele
To si ilekun iye sile fun wa

All: Yin Oluwa, iyin Oluwa
F'iyin fun Oluwa
Yin Oluwa, yin Oluwa
Eyo ni wa ju re
Ka to Baba wa lo
Loruko Jesu
Jeka jo f'ogo fun Onise yanu

Pre-Chorus
Ogo f'Olukore
Ogo! Ogo! Ogo!
Ogo f'Olukore
Ogo! Ogo! Ogo!
Ogo f'Olukore
Awa yin O l'ogo

(Acapella Vocal)
All: Ejeka ka fi inu didun
Yin Oluwa Olore
Anu re o wa titi
Lododo daju daju
Anu re o wa titi
Lododo daju daju

Pre-Chorus (Repeat with Build-up)

Ogo f'Olukore
Ogo! Ogo! Ogo!
Ogo f'Olukore
Ogo! Ogo! Ogo!
Ogo f'Olukore
Awa yin O l'ogo

Final Chorus (Repeat \u0026 Vamp)

E fiyin fun Olorun
E je ka jo fiyin fun Olorun
Ope ati iyin fun Baba
Olore a ki i ka tan ni
Olorun ayo, a juba re

(Repeat as led)
Olorun ayo, a juba re
Olorun ayo, a juba re
Olorun ayo, a juba re

End: Amope wa Ọlọrun (2x)
Ajinde ati iye aye wa ooo
Amu iyin wa